You are on page 1of 1

Oye kuse-kuse-kuse

Awo ile Olomu-Aperan


Dia fun Olomu Aperan
Nijo ire ilee won ti si lo
Ebo ni won ni ki won waa se
O gb’ebo, o ru’bo
Ire aje to ti si lo l’Omu nbo wa Ifa
Oye kuse-kuse-kuse o
Iwo lawo ile Olomu
Ire Aya to ti si lo l’Omu nbo wa Ifa
Oye kuse-kuse-kuse o
Iwo lawo ile Olomu
Ire Omo to ti si lo l’Omu nbo wa Ifa
Oye kuse-kuse-kuse o
Iwo lawo ile Olomu
Ire gbogbo to ti si lo l’Omu nbo wa Ifa

You might also like